Jó 15

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YOR)

1 Ìgbà náà ní Elifasi, ará Temani, dáhùn wí pé,

2 “Ọlọ́gbọ́n a máa sọ̀rọ̀ ìmọ̀ asán

3 Òun lè máa fi àròyé sọ̀rọ̀ tí kò ní èrè,

4 Ṣùgbọ́n ìwọ ṣá ìbẹ̀rù tì,

5 Nítorí pé ẹnu ara rẹ̀ ni ó jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀,

6 Ẹnu ara rẹ̀ ni ó dá lẹ́bi, kì í ṣe èmi;

7 “Ìwọ ha í ṣe ọkùnrin tí a kọ́ bí?

8 Ìwọ gbúròó àṣírí Ọlọ́run rí?

9 Kí ni ìwọ mọ̀ tí àwa kò mọ̀?

10 Àwọn arúgbó àti ògbólógbòó ènìyàn wà pẹ̀lú wa,

11 Ìtùnú Ọlọ́run ha kéré lọ́dọ̀ rẹ?

12 Èéṣe ti ọkàn rẹ fi ń ti ọ kiri,

13 Tí ìwọ fi yí ẹ̀mí rẹ padà lòdì sí Ọlọ́run,

14 “Kí ni ènìyàn tí ó fi jẹ mímọ́,

15 Kíyèsi i, bi Ọlọ́run ko ba gbẹ́kẹ̀lé àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀,

16 mélòó mélòó ni ènìyàn, ẹni ìríra àti eléèérí,

17 “Èmi ó fihàn ọ́, gbọ́ ti èmi;

18 ohun tí àwọn ọlọ́gbọ́n ti pa ní ìtàn láti

19 Àwọn tí a fi ilẹ̀ ayé fún nìkan,

20 Ènìyàn búburú ń ṣe làálàá,

21 Ìró ìbẹ̀rù ń bẹ ní etí rẹ̀;

22 Kò gbàgbọ́ pé òun ó jáde kúrò nínú òkùnkùn;

23 Ó ń wò káàkiri fún oúnjẹ wí pé, níbo ní ó wà?

24 Ìpọ́njú pẹ̀lú ìrora ọkàn yóò mú un bẹ̀rù,

25 Nítorí pé ó ti nawọ́ rẹ̀ jáde lòdì sí Ọlọ́run,

26 ó súre, ó sì fi ẹ̀yìn gíga,

27 “Nítorí tí òun fi ọ̀rá rẹ̀ bo ara rẹ̀ lójú,

28 Òun sì gbé inú ahoro ìlú,

29 Òun kò lé di ọlọ́rọ̀, bẹ́ẹ̀ ohun ìní rẹ̀ kò

30 Òun kì yóò jáde kúrò nínú òkùnkùn;

31 Kí òun kí ó má ṣe gbẹ́kẹ̀lé asán, kí ó má sì ṣe tan ara rẹ̀ jẹ.

32 A ó mú un ṣẹ ṣáájú pípé ọjọ́ rẹ̀,

33 Yóò dàbí àjàrà tí a gbọn èso àìpọ́n rẹ̀ dànù,

34 Nítorí pé ayọ̀ àwọn àgàbàgebè yóò túká,

35 Wọ́n lóyún ìwà ìkà, wọ́n sì bí ẹ̀ṣẹ̀,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado

Estude este capítulo no WhatsApp

Peça à IA da Bíblia Fala para explicar Jó 15, comparar traduções ou montar um estudo — tudo direto pelo WhatsApp.