Salmos 59

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YOR)

1 Gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá à mi, Ọlọ́run;

2 Gbà mí lọ́wọ́ àwọn oníṣẹ́ búburú

3 Wò ó, bí wọ́n ṣe ba ní bùba dè mí!

4 Èmi kò ṣe àìṣedéédéé kan, síbẹ̀ wọ́n sáré wọ́n ṣetán láti kọlù mí.

5 Olúwa Ọlọ́run Alágbára,

6 Wọ́n padà ní àṣálẹ́,

7 Kíyèsi ohun tí wọ́n tú jáde ní ẹnu:

8 Ṣùgbọ́n ìwọ, Olúwa, yóò fi wọ́n rẹ́rìn-ín,

9 Ìwọ agbára mi, èmi ó máa kọrin ìyìn sí ọ;

10 Ọlọ́run àánú mi ni yóò ṣáájú mi.

11 Ṣùgbọ́n má ṣe pa wọ́n, Olúwa asà wa,

12 Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ẹnu wọn,

13 pa wọ́n run nínú ìbínú,

14 Wọ́n padà ní àṣálẹ́,

15 Wọ́n ń rin kiri fún oúnjẹ

16 Ṣùgbọ́n èmi ó kọrin agbára rẹ,

17 Ìwọ agbára mi, èmi ó kọrin ìyìn sí ọ;

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado

Estude este capítulo no WhatsApp

Peça à IA da Bíblia Fala para explicar Salmos 59, comparar traduções ou montar um estudo — tudo direto pelo WhatsApp.