Neemias 7
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YOR) vs NVI
1 Lẹ́yìn ìgbà tí a tún odi mọ tán tí mo sì ri àwọn ìlẹ̀kùn sí ààyè wọn, a sì yan àwọn aṣọ́bodè, àwọn akọrin àti àwọn Lefi.
1 Depois que o muro foi reconstruído e que eu coloquei as portas no lugar, foram nomeados os porteiros, os cantores e os levitas.
2 Mo fún Hanani arákùnrin mi pẹ̀lú Hananiah olórí ilé ìṣọ́ ní àṣẹ lórí Jerusalẹmu, nítorí tí ó jẹ́ ènìyàn olóòtítọ́, ó sì bẹ̀rù Ọlọ́run jù bí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ti ṣe lọ.
2 Para governar Jerusalém encarreguei o meu irmão Hanani e, com ele, Hananias, comandante da cidade forte, pois Hananias era íntegro e temia a Deus mais do que a maioria dos homens.
3 Mo sọ fún wọn pé, “A kò gbọdọ̀ ṣí ìlẹ̀kùn Jerusalẹmu títí oòrùn yóò fi mú. Nígbà tí àwọn aṣọ́bodè bá sì wà lẹ́nu iṣẹ́, jẹ́ kí wọn ti ìlẹ̀kùn kí wọn sì há wọn. Bákan náà, yàn nínú àwọn tí ń gbé Jerusalẹmu gẹ́gẹ́ bí olùṣọ́. Àwọn mìíràn níbi tí a pín wọn sí àti àwọn mìíràn ní tòsí ilé e wọn.”
3 Eu lhes disse: As portas de Jerusalém não deverão ser abertas enquanto o sol não estiver alto. E antes de deixarem o serviço, os porteiros deverão fechar e travar as portas. Também designei moradores de Jerusalém para sentinelas, alguns em postos no muro, outros em frente das suas casas.
4 Ìlú náà tóbi ó sì ní ààyè, ṣùgbọ́n ènìyàn inú rẹ̀ kéré, a kò sì tí ì tún àwọn ilé inú rẹ̀ kọ́.
4 Ora, a cidade era grande e espaçosa, mas havia poucos moradores, e as casas ainda não tinham sido reconstruídas.
5 Nígbà náà ni Ọlọ́run mi fi sí mi ní ọkàn láti kó àwọn ọlọ́lá, àwọn ìjòyè, àti àwọn ènìyàn jọ fún ìforúkọsílẹ̀ ní ìdílé ìdílé. Mo rí ìwé àkọsílẹ̀ ìtàn ìran àwọn tí ó kọ́ gòkè padà wá láti ìgbèkùn. Èyí ni ohun tí mo rí tí a kọ sínú ìwé náà.
5 Por isso o meu Deus pôs no meu coração reunir os nobres, os oficiais e todo o povo para registrá-los por famílias. Encontrei o registro genealógico dos que foram os primeiros a voltar. E assim estava registrado ali:
6 Èyí ni àwọn ènìyàn agbègbè náà tí wọ́n sọ̀kalẹ̀ wá láti ìgbèkùn, àwọn tí Nebukadnessari ọba Babeli ti kó ní ìgbèkùn (wọ́n padà sí Jerusalẹmu àti Juda, olúkúlùkù sí ìlú u rẹ̀.
6 Estes são os homens da província que voltaram do exílio, os quais Nabucodonosor, rei da Babilônia, havia levado prisioneiros. Eles voltaram para Jerusalém e para Judá, cada um para a sua própria cidade,
7 Wọ́n jọ rìn wá pẹ̀lú u Serubbabeli, Jeṣua, Nehemiah, Asariah, Raamiah, Nahamani, Mordekai, Bilṣani, Misperi, Bigfai, Nehumu, àti Baanah).
7 em companhia de Zorobabel, Jesua, Neemias, Azarias, Raamias, Naamani, Mardoqueu, Bilsã, Misperete, Bigvai, Neum e Baaná. E esta é a lista e o número dos que retornaram, pelos chefes de família e respectivas cidades:
8 àwọn ọmọ
8 os descendentes de Parós 2. 172
9 Ṣefatia jẹ́ òjìdínnírinwó ó lé méjìlá (372)
9 de Sefatias 372
10 Arah jẹ́ ẹgbẹ̀tàléláàádọ́ta ó lé méjì (652)
10 de Ara 652
11 Pahati-Moabu (láti ipasẹ̀ ọmọ Jeṣua àti Joabu) jẹ́ ẹgbàá mẹ́rìnlá ó lé méjìdínlógún (2,818)
11 de Paate-Moabe, por meio da linhagem de Jesua e Joabe, 2. 818
12 Elamu jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀fà ó lé mẹ́rin (1,254)
12 de Elão 1. 254
13 Sattu jẹ́ òjìlélẹ́gbẹ̀rin ó lé márùn-ún (845)
13 de Zatu 845
14 Sakkai jẹ́ òjìdínlẹ́gbẹ̀rin (760)
14 de Zacai 760
15 Binnui jẹ́ òjìlélẹ́gbẹ̀ta ó lé mẹ́jọ (648)
15 de Binui 648
16 Bebai jẹ́ ẹgbẹ̀ta ó lé méjìdínlọ́gbọ̀n (628)
16 de Bebai 628
17 Asgadi jẹ́ ẹgbẹ̀ta ó dín méjìdínlọ́gọ́rin (2,322)
17 de Azgade 2. 322
18 Adonikami jẹ́ ọ̀tàlélẹ́gbẹ̀ta ó lé méje (667)
18 de Adonicão 667
19 Bigfai jẹ́ ẹgbàá ó lé mẹ́tàdínláàádọ́rin (2,067)
19 de Bigvai 2. 067
20 Adini jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀ta ó lé márùn-ún (655)
20 de Adim 655
21 Ateri (láti ipasẹ̀ Hesekiah) jẹ́ méjìdínlọ́gọ́rùn-ún (98)
21 de Ater, por meio de Ezequias, 98
22 Haṣumu jẹ́ ọ̀rìndínnírinwó ó lé mẹ́jọ (328)
22 de Hasum 328
23 Besai jẹ́ ọ̀rìndínnírinwó ó lé mẹ́rin (324)
23 de Besai 324
24 Harifu jẹ́ méjìléláàádọ́fà (112)
24 de Harife 112
25 Gibeoni jẹ́ márùndínlọ́gọ́rùn (95).
25 de Gibeom 95
26 Àwọn ọmọ
26 das cidades de Belém e de Netofate 188
27 Anatoti jẹ́ méjìdínláàádóje (128)
27 de Anatote 128
28 Beti-Asmafeti jẹ́ méjìlélógójì (42)
28 de Bete-Azmavete 42
29 Kiriati-Jearimu, Kefira, àti Beeroti jẹ́ ọ̀tàdínlẹ́gbẹ̀rin ó lé mẹ́ta (743)
29 de Quiriate-Jearim, Cefira e Beerote 743
30 Rama àti Geba jẹ́ ẹgbẹ̀ta ó lé mọ́kànlélógún (621)
30 de Ramá e Geba 621
31 Mikmasi jẹ́ méjìlélọ́gọ́fà (122)
31 de Micmás 122
32 Beteli àti Ai jẹ́ mẹ́tàlélọ́gọ́fà (123)
32 de Betel e Ai 123
33 Nebo mìíràn jẹ́ méjìléláàádọ́ta (52)
33 do outro Nebo 52
34 Elamu mìíràn jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́rìnléláàádọ́ta (1,254)
34 do outro Elão 1. 254
35 Harimu jẹ́ ọ̀rìndínnírinwó (320)
35 de Harim 320
36 Jeriko jẹ́ ọ̀tàdínnírinwó ó lé márùn-ún (345).
36 de Jericó 345
37 Lodi, Hadidi, àti Ono jẹ́ ọ̀rìndínlẹ́gbẹ̀rin ó lé ọ̀kan (721)
37 de Lode, Hadide e Ono 721
38 Senaa jẹ́ ẹgbàajì ó dín àádọ́rin (3,930).
38 de Senaá 3. 930.
39 Àwọn àlùfáà:
39 Os sacerdotes: os descendentes de Jedaías, por meio da família de Jesua, 973
40 Immeri jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀rún ó lé méjì (1,052)
40 de Imer 1. 052
41 Paṣuri jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́tàdínláàádọ́ta (1,247)
41 de Pasur 1. 247
42 Harimu jẹ́ ẹgbẹ̀rún ó lé mẹ́tàdínlógún (1,017).
42 de Harim 1. 017.
43 Àwọn ọmọ Lefi:
43 Os levitas: os descendentes de Jesua, por meio de Cadmiel, pela linhagem de Hodeva 74.
44 Àwọn akọrin:
44 Os cantores: os descendentes de Asafe 148.
45 Àwọn aṣọ́nà:
45 Os porteiros do templo: os descendentes de Salum, Ater, Talmom, Acube, Hatita e Sobai 138.
46 Àwọn ìránṣẹ́ tẹmpili.
46 Os servidores do templo: os descendentes de Zia, Hasufa, Tabaote,
47 Kerosi, Sia, Padoni,
47 Queros, Sia, Padom,
48 Lebana, Hagaba, Ṣalmai,
48 Lebana, Hagaba, Salmai,
49 Hanani, Giddeli, Gahari,
49 Hanã, Gidel, Gaar,
50 Reaiah, Resini, Nekoda,
50 Reaías, Rezim, Necoda,
51 Gassamu, Ussa, Pasea,
51 Gazão, Uzá, Paséia,
52 Besai, Mehuni, Nefisimu,
52 Besai, Meunim, Nefusim,
53 Bakbu, Hakufa, Harhuri,
53 Baquebuque, Hacufa, Harur,
54 Basluti, Mehida, Harṣa,
54 Baslite, Meída, Harsa,
55 Barkosi, Sisera, Tema,
55 Barcos, Sísera, Tamá,
56 Nesia, àti Hatifa.
56 Nesias e Hatifa.
57 Àwọn ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Solomoni:
57 Os descendentes dos servos de Salomão: os descendentes de Sotai, Soferete, Perida,
58 Jaala, Darkoni, Giddeli,
58 Jaala, Darcom, Gidel,
59 Ṣefatia, Hattili,
59 Sefatias, Hatil, Poquerete-Hazebaim e Amom.
60 Àwọn ìránṣẹ́ tẹmpili àti àwọn ọmọ ìránṣẹ́ Solomoni jẹ́ irinwó ó dín mẹ́jọ (392).
60 Os servos do templo e os descendentes dos servos de Salomão 392.
61 Àwọn wọ̀nyí gòkè wá láti àwọn ìlú ti Teli-Mela, Teli-Harṣa, Kerubu, Addoni àti Immeri, ṣùgbọ́n wọn kò lè sọ pẹ̀lú ìdánilójú pé ìdílé àwọn wá láti ara ìran ẹ̀yà Israẹli.
61 Os que chegaram das cidades de Tel-Melá, Tel-Harsa, Querube, Adom e Imer, mas não puderam provar que suas famílias eram descendentes de Israel:
62 Àwọn ọmọ
62 Os descendentes de Delaías, Tobias e Necoda 642.
63 Lára àwọn àlùfáà ni:
63 E dentre os sacerdotes: os descendentes de Habaías, Coz e Barzilai, homem que se casou com uma filha de Barzilai, de Gileade, e que era chamado por aquele nome.
64 Àwọn wọ̀nyí wá àkọsílẹ̀ orúkọ ìran wọn, ṣùgbọ́n wọn kò rí í níbẹ̀, fún ìdí èyí, a yọ wọ́n kúrò nínú àwọn tí ń ṣiṣẹ́ àlùfáà gẹ́gẹ́ bí aláìmọ́.
64 Esses procuraram seus registros de família, mas não conseguiram achá-los e, dessa forma, foram considerados impuros para o sacerdócio.
65 Baálẹ̀ sọ fún wọn nítorí náà pé wọn kò gbọdọ̀ kópa nínú jíjẹ oúnjẹ mímọ́ títí tí àlùfáà tí yóò wá tí ń ṣiṣẹ́ ìránṣẹ́ pẹ̀lú Urimu àti Tumimu yóò fi dé.
65 Por isso o governador determinou que eles não comessem das ofertas santíssimas enquanto não houvesse um sacerdote para consultar o Urim e o Tumim.
66 Gbogbo ìjọ ènìyàn náà jẹ́ ẹgbàá mọ́kànlélógún ó lé òjìdínnírinwó (42,360),
66 O total de todos os registrados foi 42. 360 homens,
67 yàtọ̀ sí àwọn ìránṣẹ́kùnrin àti ìránṣẹ́bìnrin tí wọ́n jẹ́ ẹgbẹ̀ta dín lẹ́gbàárin ó dín ẹ̀tàlélọ́gọ́ta (7,337); wọ́n sì tún ní àwọn akọrin ọkùnrin àti obìnrin tí wọ́n jẹ́ òjìlúgba ó lé márùn-ún (245).
67 além de seus 7. 337 servos e servas; havia entre eles 245 cantores e cantoras.
68 Ẹṣin wọn jẹ́ ọ̀tàdínlẹ́gbẹ̀rin ó dín mẹ́rin (736), ìbákasẹ wọn jẹ́ òjìlúgba ó dín márùn-ún (245);
68 Possuíam 736 cavalos, 245 mulas,
69 ìbákasẹ wọn jẹ́ òjìlénírinwó ó dín márùn-ún (435); kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọ́n jẹ́ ẹgbẹ̀rìnlélọ́gbọ̀n ó dín ọgọ́rin (6,720).
69 435 camelos e 6. 720 jumentos.
70 Díẹ̀ lára àwọn olórí ìdílé náà kópa nínú ṣíṣe iṣẹ́ náà. Baálẹ̀ fún ilé ìṣúra ní ẹgbẹ̀rún (1,000) dariki wúrà, àádọ́ta àwo koto àti ọ̀rìndínlẹ́gbẹ̀ta lé mẹ́wàá (530) ẹ̀wù fún àwọn àlùfáà.
70 Alguns dos chefes das famílias contribuíram para o trabalho. O governador deu à tesouraria oito quilos de ouro, 50 bacias e 530 vestes para os sacerdotes.
71 Díẹ̀ lára àwọn olórí ìdílé fún ilé ìṣúra ní ogún ẹgbẹ̀rún (20,000) dariki wúrà àti ẹgbọ̀kànlá (2,200) mina fàdákà.
71 Alguns dos chefes das famílias deram à tesouraria, para a realização do trabalho, cento e sessenta quilos de ouro e uma tonelada e trezentos e vinte quilos de prata.
72 Àròpọ̀ gbogbo ohun tí àwọn ènìyàn tókù fi sílẹ̀ jẹ́ ogún ẹgbẹ̀rún (20,000) dariki wúrà, ẹgbẹ̀rún méjì (2,000) mina fàdákà àti ẹẹ́tàdínláàdọ́rin ẹ̀wù fún àwọn àlùfáà.
72 O total dado pelo restante do povo foi de cento e sessenta quilos de ouro, uma tonelada e duzentos quilos de prata e 67 vestes para os sacerdotes.
73 Àwọn àlùfáà, àwọn Lefi, àwọn aṣọ́bodè, àwọn akọrin, àwọn ènìyàn díẹ̀, àwọn ìránṣẹ́ ilé Ọlọ́run, àti gbogbo ènìyàn Israẹli wà ní ìlú wọn.
73 Os sacerdotes, os levitas, os porteiros, os cantores e os servidores do templo, e também alguns do povo e os demais israelitas, estabeleceram-se em suas próprias cidades. Quando chegou o sétimo mês e os israelitas tinham se instalado em suas cidades,
Atalhos do teclado
- Capítulo anterior←
- Próximo capítulo→
- Versículo anteriork
- Próximo versículoj
- Limpar seleçãoEsc
- Esta ajuda?
Estude este capítulo no WhatsApp
Peça à IA da Bíblia Fala para explicar Neemias 7, comparar traduções ou montar um estudo — tudo direto pelo WhatsApp.