Esdras 2

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YOR) vs NVI

Sair da comparação
NVI Nova Versão Internacional
1 Lákòókò náà, wọ̀nyí ni àwọn ènìyàn agbègbè Juda tí ó gòkè wá láti ìgbèkùn láàrín àwọn tí a kó lọ, ẹni tí Nebukadnessari ọba Babeli ti fi agbára mú ní ìgbèkùn lọ sí Babeli (wọ́n padà sí Jerusalẹmu àti Juda, olúkúlùkù sí ìlú rẹ̀.
1 Esta é a lista dos homens da província que Nabucodonosor, rei da Babilônia, tinha levado prisioneiros para a Babilônia. Eles voltaram para Jerusalém e Judá, cada um para a sua própria cidade.
2 Àwọn wọ̀nyí bá Serubbabeli, Jeṣua, Nehemiah, Seraiah, Reelaiah, Mordekai, Bilṣani, Mispari, Bigfai, Rehumu àti Baanah wá).
2 Vieram na companhia de Zorobabel, Jesua, Neemias, Seraías, Reelaías, Mardoqueu, Bilsã, Mispar, Bigvai, Reum e Baaná. Esta é a lista dos israelitas:
3 Àwọn ọmọ
3 os descendentes de Parós 2. 172
4 Ṣefatia jẹ́ òjìdínnírinwó ó lé méjìlá (372)
4 de Sefatias 372
5 Arah jẹ́ ẹgbẹ̀rin ó dín mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (775)
5 de Ara 775
6 Pahati-Moabu (láti ipasẹ̀ àwọn ọmọ Jeṣua àti Joabu) jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjì àti ẹgbẹ̀rin lé méjìlá (2,812)
6 de Paate-Moabe, por meio da linhagem de Jesua e Joabe, 2. 812
7 Elamu jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀fà ó lé mẹ́rin (1,254)
7 de Elão 1. 254
8 Sattu jẹ́ ọ̀tàdínlẹ́gbẹ̀rún ó lé márùn-ún (945)
8 de Zatu 945
9 Sakkai jẹ́ òjìdínlẹ́gbẹ̀rin (760)
9 de Zacai 760
10 Bani jẹ́ òjìlélẹ́gbẹ̀ta ó lé méjì (642)
10 de Bani 642
11 Bebai jẹ́ ẹgbẹ̀ta ó lé mẹ́tàlélógún (623)
11 de Bebai 623
12 Asgadi jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé méjìlélógún (1,222)
12 de Azgade 1. 222
13 Adonikami jẹ́ ọ̀tàlélẹ́gbẹ̀ta ó lé mẹ́fà (666)
13 de Adonicão 666
14 Bigfai jẹ́ ẹgbàá ó lé mẹ́rìndínlọ́gọ́ta (2,056)
14 de Bigvai 2. 056
15 Adini jẹ́ àádọ́ta lé ní irinwó ó lé mẹ́rin (454)
15 de Adim 454
16 Ateri (nípasẹ̀ Hesekiah) jẹ́ méjìdínlọ́gọ́run (98)
16 de Ater, por meio de Ezequias, 98
17 Besai jẹ́ ọrùndínnírinwó ó lé mẹ́ta (323)
17 de Besai 323
18 Jora jẹ́ méjìléláàádọ́fà (112)
18 de Jora 112
19 Haṣumu jẹ́ igba ó lé mẹ́tàlélógún (223)
19 de Hasum 223
20 Gibbari jẹ́ márùndínlọ́gọ́rùn (95).
20 de Gibar 95
21 Àwọn ọmọ
21 os da cidade de Belém 123
22 Netofa jẹ́ mẹ́rìndínlọ́gọ́ta (56)
22 de Netofate 56
23 Anatoti jẹ́ méjìdínláàádóje (128)
23 de Anatote 128
24 Asmafeti jẹ́ méjìlélógójì (42)
24 de Azmavete 42
25 Kiriati-Jearimu, Kefira àti Beeroti jẹ́ ọ̀tàdínlẹ́gbẹ̀rin ó lé mẹ́ta (743)
25 de Quiriate-Jearim, Quefira e Beerote 743
26 Rama àti Geba jẹ́ ẹgbẹ̀ta ó lé mọ́kànlélógún (621)
26 de Ramá e Geba 621
27 Mikmasi jẹ́ méjìlélọ́gọ́fà (122)
27 de Micmás 122
28 Beteli àti Ai jẹ́ igba ó lé mẹ́tàlélógún (223)
28 de Betel e Ai 223
29 Nebo jẹ́ méjìléláàádọ́ta (52)
29 de Nebo 52
30 Magbiṣi jẹ́ mẹ́rìndínlọ́gọ́jọ (156)
30 de Magbis 156
31 Elamu mìíràn jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́rìnléláàádọ́ta (1,254)
31 da outra Elão 1. 254
32 Harimu jẹ́ ọ̀rìndínnírinwó (320).
32 de Harim 320
33 Lodi, Hadidi àti Ono jẹ́ ọ̀rìndínlẹ́gbẹ̀rin ó lé márùn-ún (725)
33 de Lode, Hadide e Ono 725
34 Jeriko jẹ́ ọ̀tàdínnírinwó ó lé márùn-ún (345)
34 de Jericó 345
35 Senaa jẹ́ egbèji dín lógún ó lé ọgbọ̀n (3,630).
35 de Senaá 3. 630
36 Àwọn àlùfáà.
36 Os sacerdotes: os descendentes de Jedaías, por meio da família de Jesua 973
37 Immeri jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀rún ó lé méjì (1,052)
37 de Imer 1. 052
38 Paṣuri jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́tàdínláàádọ́ta (1,247)
38 de Pasur 1. 247
39 Harimu jẹ́ ẹgbẹ̀rún ó lé mẹ́tàdínlógún (1,017).
39 de Harim 1. 017
40 Àwọn ọmọ Lefi.
40 Os levitas: os descendentes de Jesua e de Cadmiel, por meio da linhagem de Hodavias 74
41 Àwọn akọrin.
41 Os cantores: os descendentes de Asafe 128
42 Àwọn aṣọ́bodè.
42 Os porteiros do templo: os descendentes de Salum, Ater, Talmom, Acube, Hatita e Sobai 139
43 Àwọn ìránṣẹ́ tẹmpili.
43 Os servidores do templo: os descendentes de Zia, Hasufa, Tabaote,
44 Kerosi, Siaha, Padoni,
44 Queros, Sia, Padom,
45 Lebana, Hagaba, Akkubu,
45 Lebana, Hagaba, Acube,
46 Hagabu, Ṣalmai, Hanani,
46 Hagabe, Sanlai, Hanã,
47 Giddeli, Gahari, Reaiah,
47 Gidel, Gaar, Reaías,
48 Resini, Nekoda, Gassamu,
48 Rezim, Necoda, Gazão,
49 Ussa, Pasea, Besai,
49 Uzá, Paséia, Besai,
50 Asna, Mehuni, Nefisimu,
50 Asná, Meunim, Nefusim,
51 Bakbu, Hakufa, Harhuri.
51 Bacbuque, Hacufa, Harur,
52 Basluti, Mehida, Harṣa,
52 Baslute, Meída, Harsa,
53 Barkosi, Sisera, Tema,
53 Barcos, Sísera, Tamá,
54 Nesia àti Hatifa.
54 Nesias e Hatifa.
55 Àwọn ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Solomoni.
55 Os descendentes dos servos de Salomão: os descendentes de Sotai, Soferete, Peruda,
56 Jaala, Darkoni, Giddeli,
56 Jaala, Darcom, Gidel,
57 Ṣefatia, àwọn ọmọ Hattili,
57 Sefatias, Hatil, Poquerete-Hazebaim e Ami.
58 Àwọn ìránṣẹ́ tẹmpili àti àwọn ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Solomoni jẹ́ irinwó ó dín mẹ́jọ (392).
58 O total dos servidores do templo e dos descendentes dos servos de Salomão 392
59 Àwọn wọ̀nyí gòkè wá láti àwọn ìlú ti Teli-Mela, Teli-Harṣa, Kerubu, Addoni àti Immeri, ṣùgbọ́n wọn kò lè sọ pẹ̀lú ìdánilójú pé ìdílé àwọn wá láti ara ìran ẹ̀yà Israẹli.
59 Os que chegaram das cidades de Tel-Melá, Tel-Harsa, Querube, Adã e Imer, mas não puderam comprovar que suas famílias descendiam de Israel, foram os seguintes:
60 Àwọn ọmọ
60 Os descendentes de Delaías, Tobias e Necoda 652
61 Àti nínú àwọn ọmọ àwọn àlùfáà.
61 E dentre os sacerdotes: Os descendentes de Habaías, Coz e Barzilai, homem que se casou com uma filha de Barzilai, de Gileade, e que era chamado pelo nome do sogro.
62 Àwọn wọ̀nyí wá ìwé ìrántí ìdílé wọn, ṣùgbọ́n wọn kò rí i, bẹ́ẹ̀ ni a kò kà wọ́n kún ara àlùfáà nítorí, a kà wọ́n sí aláìmọ́.
62 Eles procuraram pelos seus registros de família, mas não conseguiram achá-los e foram considerados impuros para o sacerdócio.
63 Baálẹ̀ pa á láṣẹ fún wọn pé wọn kò gbọdọ̀ jẹ nínú oúnjẹ mímọ́ jùlọ títí tí àlùfáà kan yóò fi ṣiṣẹ́ ìránṣẹ́ pẹ̀lú Urimu àti Tumimu.
63 Por isso o governador os proibiu de comer alimentos sagrados enquanto não houvesse um sacerdote capaz de consultar a Deus por meio do Urim e do Tumim.
64 Gbogbo ìjọ ènìyàn náà jẹ́ ẹgbàá mọ́kànlélógún ó lé òjìdínnírinwó (42,360).
64 A totalidade dos que voltaram do exílio atingiu o número de 42. 360 homens,
65 Yàtọ̀ sí ẹgbẹ̀rin dín lẹ́gbàárin ó dín mẹ́tàlélọ́gọ́ta (7,337) ìránṣẹ́ ọkùnrin àti ìránṣẹ́bìnrin; wọ́n ní igba (200) akọrin ọkùnrin àti obìnrin.
65 além dos seus 7. 337 servos e servas; havia entre eles 200 cantores e cantoras.
66 Wọ́n ní ọ̀tàdínlẹ́gbẹ̀rin ó dín mẹ́rin ẹṣin (736); ìbáaka òjìlélúgba ó lé márùn-ún (245),
66 Possuíam 736 cavalos, 245 mulas,
67 ràkunmí jẹ́ irinwó ó lé márùndínlógójì (435) àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ ẹgbẹ̀rin lé lọ́gbọ̀n ó dín ọgọ́rin (6,720).
67 435 camelos e 6. 720 jumentos.
68 Ní ìgbà tí wọ́n dé ilé Olúwa ní Jerusalẹmu, díẹ̀ nínú àwọn olórí àwọn ìdílé fi ọrẹ àtinúwá sílẹ̀ fún ṣíṣe àtúnkọ́ ilé Ọlọ́run ní ààyè rẹ̀.
68 Quando chegaram ao templo do Senhor em Jerusalém, alguns dos chefes das famílias deram ofertas voluntárias para a reconstrução do templo de Deus no seu antigo local.
69 Gẹ́gẹ́ bí agbára wọn, wọ́n fún ilé ìṣúra fún iṣẹ́ yìí ní ọ̀kẹ́ mẹ́ta ó lé lẹ́gbẹ̀rún (61,000) ìwọ̀n dariki wúrà, ẹgbẹ̀rún márùn-ún (5,000) fàdákà àti ọgọ́rùn-ún ẹ̀wù àlùfáà.
69 De acordo com as suas possibilidades, deram à tesouraria para essa obra quinhentos quilos de ouro, três toneladas de prata e cem vestes sacerdotais.
70 Àwọn àlùfáà, àwọn ará Lefi, àwọn akọrin, àwọn aṣọ́bodè àti àwọn ìránṣẹ́ ilé Olúwa ṣe àtìpó sínú àwọn ìlú wọn, pẹ̀lú àwọn ènìyàn mìíràn, àti ìyókù àwọn ọmọ Israẹli ṣe àtìpó sínú ìlú u wọn.
70 Os sacerdotes, os levitas, os cantores, os porteiros e os servidores do templo, bem como os demais israelitas, estabeleceram-se em suas cidades de origem.

Ler em outra tradução

Comparar com outra

Estude este capítulo no WhatsApp

Peça à IA da Bíblia Fala para explicar Esdras 2, comparar traduções ou montar um estudo — tudo direto pelo WhatsApp.