Salmos 95

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YOR)

1 Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a kọ orin ayọ̀ sí Olúwa,

2 Ẹ jẹ́ kí a wá sí iwájú rẹ̀ pẹ̀lú ọpẹ́

3 Nítorí Olúwa Ọlọ́run títóbi ni,

4 Ní ọwọ́ rẹ̀ ni ọ̀gbun ilẹ̀ wà,

5 Tirẹ̀ ni Òkun, nítorí òun ni ó dá a

6 Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a foríbalẹ̀ kí a sìn ín,

7 nítorí òun ni Ọlọ́run wa,

8 “Ẹ má ṣe sé ọkàn yín le gẹ́gẹ́ bí ẹ ti ṣe ní Meriba,

9 nígbà tí àwọn baba yín dán mi wò

10 Fún ogójì ọdún ni èmi fi bínú sí ìran náà;

11 Nítorí náà ni mo kéde ìbúra nínú ìbínú mi,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado

Estude este capítulo no WhatsApp

Peça à IA da Bíblia Fala para explicar Salmos 95, comparar traduções ou montar um estudo — tudo direto pelo WhatsApp.