Oséias 2

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YOR)

1 “Sọ fún àwọn arákùnrin rẹ, ‘Ènìyàn mi,’ kí o sì wí fún àwọn arábìnrin rẹ ‘Àyànfẹ́ mi.’

2 “Ẹ bá ìyá yín wí, ẹ bá a wí,

3 Àìṣe bẹ́ẹ̀ èmi yóò tú u sí ìhòhò,

4 Èmi kò ní fi àánú mi hàn sí àwọn ọmọ rẹ̀

5 Nítorí ìyá wọn ti hùwà àgbèrè,

6 Nítorí náà, èmi ó fi ẹ̀gún dì í lọ́nà,

7 Yóò sáré lé àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ ṣùgbọ́n kò ní bá wọn;

8 Nítorí pé kò tí ì mọ̀ pé èmi ni

9 “Nítorí náà, èmi yóò mú ọkà mi kúrò nígbà tó bá pọ́n,

10 Èmi yóò sì fi ìwà ìtìjú rẹ̀ hàn

11 Èmi yóò mú gbogbo ayọ̀ rẹ̀ wá sí òpin:

12 Èmi yóò pa àjàrà àti igi ọ̀pọ̀tọ́ rẹ̀ run,

13 Èmi yóò bẹ̀ ọjọ́ Baalimu wò ní ara rẹ̀

14 “Nítorí náà, èmi yóò tàn án,

15 Níbẹ̀ ni èmi yóò ti dá ọgbà àjàrà rẹ̀ padà fún un,

16 “Yóò sì ṣe ní ọjọ́ náà,

17 Èmi yóò mú orúkọ, àwọn òrìṣà Baali kúrò lẹ́nu rẹ̀;

18 Ní ọjọ́ náà, èmi yóò ṣe májẹ̀mú

19 Èmi yóò fẹ́ ọ fún ara mi títí láé;

20 Èmi yóò fẹ́ ọ fún ara mi ní òtítọ́

21 “Èmi yóò sì dáhùn ní ọjọ́ náà,”

22 ilẹ̀ náà yóò sì dá ọkà,

23 Èmi ó sì gbìn ín fún ara mi lórí ilẹ̀ náà,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado

Estude este capítulo no WhatsApp

Peça à IA da Bíblia Fala para explicar Oséias 2, comparar traduções ou montar um estudo — tudo direto pelo WhatsApp.