Jeremias 50

Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YOR)

1 Èyí ni ọ̀rọ̀ tí Olúwa fi sẹ́nu wòlíì Jeremiah láti sọ fún ará ilẹ̀ Babeli:

2 “Ẹ sọ ọ́ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè, ẹ sì kéde,

3 Àwọn ìlú ní apá àríwá yóò

4 “Ní ọjọ́ wọ̀nyí àti ní àkókò náà,”

5 Wọn ó máa béèrè ọ̀nà Sioni,

6 “Àwọn ènìyàn mi ti jẹ́ àgùntàn tí ó sọnù,

7 Gbogbo àwọn tí ó rí wọn, ti pa wọ́n jẹ

8 “Jáde kúrò ní Babeli,

9 Nítorí pé èmi yóò ru,

10 A ó dààmú Babeli,

11 “Nítorí pé inú yín dùn nítorí pé ẹ̀yìn yọ̀,

12 Ojú yóò ti ìyá rẹ, ẹni tí ó bí ọ

13 Nítorí ìbínú Olúwa, kì yóò ní olùgbé;

14 “Dúró sí ààyè rẹ ìwọ Babeli

15 Kígbe mọ́ ọn ní gbogbo ọ̀nà!

16 Ké afúnrúgbìn kúrò ní Babeli,

17 “Israẹli jẹ́ àgùntàn tí ó ṣìnà kiri,

18 Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run Alágbára, Ọlọ́run Israẹli wí,

19 Ṣùgbọ́n, èmi yóò mú Israẹli

20 Ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì,”

21 “Kọlu ilẹ̀ Merataimu àti àwọn

22 Ariwo ogun wà ní ilẹ̀ náà

23 Báwo ni ó ṣe fọ́, tí ó sì pín yẹ́lẹyẹ̀lẹ tó,

24 Mo dẹ pàkúté sílẹ̀

25 Olúwa ti kó àwọn ohun èlò ìjà rẹ̀ jáde,

26 Ẹ wá sórí rẹ̀ láti òpin gbogbo,

27 Pa gbogbo àwọn akọ màlúù rẹ,

28 Gbọ́ ohùn àwọn tí ó sálọ, tí ó sì sálà láti Babeli wá,

29 “Pe ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn, àní gbogbo tafàtafà, sórí Babeli,

30 Nítorí náà, àwọn ọmọkùnrin rẹ̀

31 “Wò ó, èmi yóò dojú kọ ọ́ ìwọ agbéraga,”

32 Onígbèéraga yóò kọsẹ̀, yóò sì ṣubú,

33 Èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun sọ:

34 Síbẹ̀, Olùràpadà wọn, Alágbára,

35 “Idà lórí àwọn Babeli!”

36 Idà lórí àwọn wòlíì èké

37 Idà lórí àwọn kẹ̀kẹ́-ẹṣin rẹ̀

38 Ilẹ̀ gbígbẹ lórí omi rẹ̀; yóò sì gbẹ.

39 “Nítorí náà àwọn ẹranko ijù

40 Gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti gba ìjọba Sodomu àti Gomorra

41 “Wò ó! Ọ̀wọ́ ọmọ-ogun láti ìhà àríwá;

42 Wọ́n sì di ìhámọ́ra ọ̀kọ̀ àti ọrun,

43 Ọba Babeli ti gbọ́ ìròyìn nípa wọn,

44 Bí i kìnnìún ni òun ó gòkè wá láti igbó Jordani

45 Nítorí náà, gbọ́ ohun tí

46 Ní ohùn igbe ńlá pé;

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado

Estude este capítulo no WhatsApp

Peça à IA da Bíblia Fala para explicar Jeremias 50, comparar traduções ou montar um estudo — tudo direto pelo WhatsApp.